Àwọn Ọba Keji 19:30 BIBELI MIMỌ (BM)

Yóo dára fún àwọn tí wọ́n bá ṣẹ́kù ní Juda. Wọn yóo dàbí irúgbìn tí gbòǹgbò rẹ̀ wọnú ilẹ̀ lọ tí ó sì ń so èso jáde.

Àwọn Ọba Keji 19

Àwọn Ọba Keji 19:29-37