Àwọn Ọba Keji 19:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n sì jíṣẹ́ Hesekaya ọba fún Aisaya pé, “Ọba sọ pé òní jẹ́ ọjọ́ ìrora, wọ́n ń fi ìyà jẹ wá, a sì wà ninu ìtìjú. A dàbí aboyún tí ó fẹ́ bímọ ṣugbọn tí kò ní agbára tó.

Àwọn Ọba Keji 19

Àwọn Ọba Keji 19:1-7