Àwọn Ọba Keji 19:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó rán Eliakimu ati Ṣebina ati àwọn àgbààgbà alufaa, tí wọ́n fi aṣọ ọ̀fọ̀ bo ara wọn, lọ sọ́dọ̀ wolii Aisaya ọmọ Amosi.

Àwọn Ọba Keji 19

Àwọn Ọba Keji 19:1-12