Àwọn Ọba Keji 19:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn baba ńlá mi ti pa àwọn ìlú Gosani, Harani, Resefu ati àwọn ọmọ Edẹni tí wọ́n wà ní Telasari run, àwọn ọlọrun wọn kò sì lè gbà wọ́n.

Àwọn Ọba Keji 19

Àwọn Ọba Keji 19:10-13