Àwọn Ọba Keji 19:11 BIBELI MIMỌ (BM)

O ti gbọ́ ìròyìn ohun tí ọba Asiria ti ṣe sí àwọn tí ó ti bá jagun, pé ó pa wọ́n run patapata ni. Ṣé ìwọ rò pé o lè là?

Àwọn Ọba Keji 19

Àwọn Ọba Keji 19:8-17