Àwọn Ọba Keji 17:36 BIBELI MIMỌ (BM)

ṣugbọn wọ́n gbọdọ̀ bẹ̀rù OLUWA tí ó mú wọn jáde kúrò ní Ijipti pẹlu ọwọ́ agbára ńlá ati ipá. Ó ní kí wọ́n máa tẹríba fún un, kí wọn sì máa rúbọ sí i.

Àwọn Ọba Keji 17

Àwọn Ọba Keji 17:31-41