Àwọn Ọba Keji 17:35 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA bá wọn dá majẹmu, ó sì pàṣẹ fún wọn, pé, wọn kò gbọdọ̀ bọ oriṣa, tabi kí wọ́n júbà wọn, bẹ́ẹ̀ ni wọn kò gbọdọ̀ sìn wọ́n tabi kí wọ́n rúbọ sí wọn;

Àwọn Ọba Keji 17

Àwọn Ọba Keji 17:31-39