Àwọn Ọba Keji 17:28 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, ọ̀kan ninu àwọn alufaa tí wọ́n kó wá láti Samaria pada lọ, ó sì ń gbé Bẹtẹli, níbẹ̀ ni ó ti ń kọ́ àwọn eniyan náà bí wọn yóo ṣe máa sin OLUWA.

Àwọn Ọba Keji 17

Àwọn Ọba Keji 17:26-32