Àwọn Ọba Keji 17:27 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọba bá pàṣẹ, ó ní, “Ẹ dá ọ̀kan ninu àwọn alufaa tí a kó lẹ́rú pada sí Samaria, kí ó lè kọ́ àwọn eniyan náà ní òfin Ọlọrun ilẹ̀ náà.”

Àwọn Ọba Keji 17

Àwọn Ọba Keji 17:24-30