Àwọn Ọba Keji 17:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó ṣe nǹkan tí ó burú lójú OLUWA, ṣugbọn ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀ kò tó ti àwọn ọba tí wọ́n jẹ ṣáájú rẹ̀.

Àwọn Ọba Keji 17

Àwọn Ọba Keji 17:1-12