Àwọn Ọba Keji 17:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ọdún kejila tí Ahasi jọba ní Juda, ni Hoṣea ọmọ Ela jọba lórí Israẹli, ní Samaria, ó sì jọba fún ọdún mẹsan-an.

Àwọn Ọba Keji 17

Àwọn Ọba Keji 17:1-4