Àwọn Ọba Keji 17:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n ń sun turari ní gbogbo orí òkè, gẹ́gẹ́ bí ìṣe àwọn tí OLUWA lé jáde kúrò ní ilẹ̀ náà. Wọ́n mú kí ibinu OLUWA ru pẹlu ìwà burúkú wọn,

Àwọn Ọba Keji 17

Àwọn Ọba Keji 17:8-20