Àwọn Ọba Keji 17:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n gbé àwọn òpó tí a fi òkúta ṣe ati àwọn ère Aṣerimu sí orí àwọn òkè ati sí abẹ́ àwọn igi tí wọ́n ní ìbòòji.

Àwọn Ọba Keji 17

Àwọn Ọba Keji 17:2-12