Àwọn Ọba Keji 14:27 BIBELI MIMỌ (BM)

Bẹ́ẹ̀ sì ni OLUWA kò tíì sọ pé òun óo pa gbogbo Israẹli run, nítorí náà, ó ṣẹgun fún wọn láti ọwọ́ Jeroboamu ọmọ Jehoaṣi.

Àwọn Ọba Keji 14

Àwọn Ọba Keji 14:25-29