Àwọn Ọba Keji 14:26 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA rí i pé ìpọ́njú àwọn ọmọ Israẹli pọ̀, kò sì sí ẹni tí ìpọ́njú náà kò kàn, ati ẹrú ati ọmọ, bẹ́ẹ̀ ni kò sí ẹni tí ó lè ràn wọ́n lọ́wọ́.

Àwọn Ọba Keji 14

Àwọn Ọba Keji 14:16-29