Àwọn Ọba Keji 14:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Jehoaṣi kú, wọ́n sin òkú rẹ̀ sinu ibojì àwọn ọba ní Samaria. Jeroboamu ọmọ rẹ̀ sì jọba lẹ́yìn rẹ̀.

Àwọn Ọba Keji 14

Àwọn Ọba Keji 14:6-20