Àwọn Ọba Keji 14:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo nǹkan yòókù tí Jehoaṣi ṣe, ati ìwà akọni rẹ̀ ninu ogun tí ó bá Amasaya jà, ni a kọ sinu Ìwé Ìtàn Àwọn Ọba Israẹli.

Àwọn Ọba Keji 14

Àwọn Ọba Keji 14:7-25