Àwọn Ọba Keji 13:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Èyí bí Eliṣa ninu, ó sì sọ fún ọba pé, “Bí ó bá jẹ́ pé o ta ọfà náà nígbà marun-un tabi mẹfa ni, ò bá ṣẹgun Siria patapata, ṣugbọn báyìí, ìgbà mẹta ni o óo ṣẹgun wọn.”

Àwọn Ọba Keji 13

Àwọn Ọba Keji 13:13-24