Àwọn Ọba Keji 13:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Eliṣa tún ní kí ọba máa ta àwọn ọfà yòókù sílẹ̀. Nígbà tí ó ta á lẹẹmẹta, ó dáwọ́ dúró.

Àwọn Ọba Keji 13

Àwọn Ọba Keji 13:12-25