Àwọn Ọba Keji 12:14 BIBELI MIMỌ (BM)

ṣugbọn wọn ń lò ó láti fi san owó fún àwọn òṣìṣẹ́ ati láti ra àwọn ohun èlò fún àtúnṣe ilé OLUWA.

Àwọn Ọba Keji 12

Àwọn Ọba Keji 12:11-19