Àwọn Ọba Keji 12:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọn kò lò lára owó náà láti fi ra agbada fadaka, abọ́, fèrè, tabi àwọn ohun èlò wúrà tabi ti fadaka sí ilé OLUWA,

Àwọn Ọba Keji 12

Àwọn Ọba Keji 12:11-18