Àwọn Ọba Keji 12:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn tí wọ́n bá wọn owó náà, wọn yóo gbé àpò owó náà fún àwọn tí wọn ń ṣe àkóso ilé OLUWA. Àwọn ni wọn yóo san owó fún àwọn gbẹ́nàgbẹ́nà ati àwọn tí wọn ń kọ́lé;

Àwọn Ọba Keji 12

Àwọn Ọba Keji 12:4-19