Àwọn Ọba Keji 12:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí owó bá pọ̀ ninu àpótí náà, akọ̀wé ọba ati olórí Alufaa yóo ka owó náà, wọn yóo sì dì í sinu àpò.

Àwọn Ọba Keji 12

Àwọn Ọba Keji 12:1-14