Àwọn Ọba Keji 11:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo àwọn eniyan kún fún ayọ̀, gbogbo ìlú sì ní alaafia lẹ́yìn tí wọ́n ti fi idà pa Atalaya ní ààfin.

Àwọn Ọba Keji 11

Àwọn Ọba Keji 11:14-21