Àwọn Ọba Keji 11:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Òun ati àwọn olórí ogun ati àwọn tí wọ́n ń ṣọ́ ọba ati àwọn tí wọn ń ṣọ́ ààfin sin ọba láti ilé OLUWA lọ sí ààfin. Ọba gba ẹnu ọ̀nà àwọn olùṣọ́ wọlé, ó sì jókòó lórí ìtẹ́.

Àwọn Ọba Keji 11

Àwọn Ọba Keji 11:18-21