Àwọn Ọba Keji 10:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí wọ́n jíṣẹ́ fún Jehu pé wọ́n ti kó orí àwọn ọmọ Ahabu dé, ó pàṣẹ pé kí wọ́n kó wọn jọ sí ọ̀nà meji ní ẹnubodè ìlú, títí di òwúrọ̀ ọjọ́ keji.

Àwọn Ọba Keji 10

Àwọn Ọba Keji 10:1-18