Àwọn Ọba Keji 10:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí wọ́n rí ìwé Jehu gbà, àwọn olórí Samaria pa gbogbo àwọn ọmọ Ahabu, wọ́n sì kó orí wọn sinu apẹ̀rẹ̀ lọ fún Jehu ní Jesireeli.

Àwọn Ọba Keji 10

Àwọn Ọba Keji 10:2-11