Àwọn Ọba Keji 10:32 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní àkókò náà ni OLUWA bẹ̀rẹ̀ sí dín ilẹ̀ Israẹli kù. Hasaeli ọba Siria gba gbogbo àwọn agbègbè Israẹli,

Àwọn Ọba Keji 10

Àwọn Ọba Keji 10:25-36