Àwọn Ọba Keji 10:31 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn Jehu kò kíyèsára kí ó fi gbogbo ọkàn rẹ̀ tẹ̀lé Òfin OLUWA Ọlọrun Israẹli; ìwà ẹ̀ṣẹ̀ Jeroboamu tí ó mú kí Israẹli hù ni ó tẹ̀lé.

Àwọn Ọba Keji 10

Àwọn Ọba Keji 10:29-36