Àwọn Adájọ́ 9:57 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọlọrun sì mú kí gbogbo ìwà ibi àwọn ará Ṣekemu pada sórí wọn. Èpè tí Jotamu ọmọ Gideoni ṣẹ́ sì ṣẹ mọ́ wọn lára.

Àwọn Adájọ́ 9

Àwọn Adájọ́ 9:56-57