Àwọn Adájọ́ 10:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn tí Abimeleki kú, Tola ọmọ Pua, ọmọ Dodo, láti inú ẹ̀yà Isakari ni ó dìde tí ó sì gba Israẹli kalẹ̀. Ìlú Ṣamiri tí ó wà ní agbègbè olókè ti Efuraimu ni ìlú rẹ̀.

Àwọn Adájọ́ 10

Àwọn Adájọ́ 10:1-2