Àwọn Adájọ́ 9:53 BIBELI MIMỌ (BM)

Obinrin kan bá gbé ọmọ ọlọ kan, ó sọ ọ́ sílẹ̀, ọmọ ọlọ yìí bá Abimeleki lórí, ó sì fọ́ agbárí rẹ̀.

Àwọn Adájọ́ 9

Àwọn Adájọ́ 9:46-54