Àwọn Adájọ́ 9:52 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Abimeleki dé ibi ilé ìṣọ́ náà, ó gbógun tì í. Ó súnmọ́ ẹnu ọ̀nà ilé ìṣọ́ náà láti dáná sun ún.

Àwọn Adájọ́ 9

Àwọn Adájọ́ 9:47-57