Àwọn Adájọ́ 9:46 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí gbogbo àwọn tí wọ́n ń gbé ilé ìṣọ́ tí ó wà ní Ṣekemu gbọ́, wọ́n sá lọ sí ibi ààbò tí ó wà ní ilé Eli-beriti.

Àwọn Adájọ́ 9

Àwọn Adájọ́ 9:37-49