Àwọn Adájọ́ 9:45 BIBELI MIMỌ (BM)

Abimeleki gbógun ti ìlú náà ní gbogbo ọjọ́ náà, ó gbà á, ó sì pa àwọn eniyan inú rẹ̀; ó wó gbogbo ìlú náà palẹ̀, ó sì da iyọ̀ sí i.

Àwọn Adájọ́ 9

Àwọn Adájọ́ 9:44-49