Àwọn Adájọ́ 8:25 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n dá a lóhùn pé, “A óo fi tayọ̀tayọ̀ kó wọn fún ọ.” Wọ́n bá tẹ́ aṣọ kan sílẹ̀, olukuluku sì bẹ̀rẹ̀ sí ju yẹtí tí ó wà ninu ìkógun rẹ̀ sibẹ.

Àwọn Adájọ́ 8

Àwọn Adájọ́ 8:17-29