Àwọn Adájọ́ 8:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Gideoni dá wọn lóhùn, ó ní “N kò ní jọba lórí yín, bẹ́ẹ̀ ni ọmọ mi kò ní jọba lórí yín, OLUWA ni yóo máa jọba lórí yín.”

Àwọn Adájọ́ 8

Àwọn Adájọ́ 8:19-31