Àwọn Adájọ́ 8:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó bá pe Jeteri àkọ́bí rẹ̀, ó ní, “Dìde, kí o sì pa wọ́n,” ṣugbọn ọmọ náà kò fa idà rẹ̀ yọ nítorí pé ẹ̀rù ń bà á, nítorí ọmọde ni.

Àwọn Adájọ́ 8

Àwọn Adájọ́ 8:18-26