Àwọn Adájọ́ 8:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó dáhùn, ó ní, “Arakunrin mi ni wọ́n, ìyá kan náà ni ó bí wa. Bí OLUWA ti wà láàyè, bí ó bá jẹ́ pé ẹ dá wọn sí ni, ǹ bá dá ẹ̀yin náà sí.”

Àwọn Adájọ́ 8

Àwọn Adájọ́ 8:17-24