Àwọn Adájọ́ 8:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Seba ati Salimuna bá bẹ̀rẹ̀ sí sá lọ, ṣugbọn Gideoni lé àwọn ọba Midiani mejeeji yìí títí tí ó fi mú wọn. Jìnnìjìnnì bá dàbo gbogbo àwọn ọmọ ogun wọn.

Àwọn Adájọ́ 8

Àwọn Adájọ́ 8:8-14