Àwọn Adájọ́ 7:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó wí fún wọn pé, “Ẹ máa wò mí, kí ẹ sì máa ṣe bí mo bá ti ń ṣe. Nígbà tí mo bá dé ìkangun àgọ́ náà, ẹ ṣe bí mo bá ti ṣe.

Àwọn Adájọ́ 7

Àwọn Adájọ́ 7:9-25