Àwọn Adájọ́ 7:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó pín àwọn ọọdunrun (300) náà sí ọ̀nà mẹta, ó fi fèrè ogun ati ìkòkò òfìfo tí wọn fi ògùṣọ̀ sí ninu lé ẹnìkọ̀ọ̀kan wọn lọ́wọ́.

Àwọn Adájọ́ 7

Àwọn Adájọ́ 7:15-24