Àwọn Adájọ́ 6:30 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ará ìlú náà bá wí fún Joaṣi pé, “Mú ọmọ rẹ jáde kí á pa á, nítorí pé ó ti wó pẹpẹ oriṣa Baali, ó sì ti gé ère oriṣa Aṣera tí ó wà ní ẹ̀gbẹ́ rẹ̀.”

Àwọn Adájọ́ 6

Àwọn Adájọ́ 6:21-34