Àwọn Adájọ́ 6:29 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n bá ń bi ara wọn léèrè pé, “Ta ló dán irú èyí wò?” Lẹ́yìn ìgbà tí wọn ti wádìí, wọ́n ní, “Gideoni ọmọ Joaṣi ni ó ṣe é.”

Àwọn Adájọ́ 6

Àwọn Adájọ́ 6:25-34