Àwọn Adájọ́ 5:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹni ibukun jùlọ ni Jaeli láàrin àwọn obinrin,Jaeli, aya Heberi, ọmọ Keni,ẹni ibukun jùlọ láàrin àwọn obinrin tí ń gbé inú àgọ́.

Àwọn Adájọ́ 5

Àwọn Adájọ́ 5:19-27