Àwọn Adájọ́ 5:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Angẹli OLUWA ní, “Ìlú ègún ni ìlú Merosi,ẹni ègún burúkú sì ni àwọn olùgbé rẹ̀,nítorí pé wọ́n kọ̀, wọn kò wá ran OLUWA lọ́wọ́;wọn kò ran OLUWA lọ́wọ́ láti gbógun ti àwọn alágbára.”

Àwọn Adájọ́ 5

Àwọn Adájọ́ 5:17-26