Àwọn Adájọ́ 5:1-2 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Debora ati Baraki ọmọ Abinoamu bá kọrin ní ọjọ́ náà pé:

2. Ẹ fi ìyìn fún OLUWA,nítorí pé, àwọn olórí ni wọ́n ṣiwaju ní Israẹli,àwọn eniyan sì fi tọkàntọkàn fa ara wọn kalẹ̀.

Àwọn Adájọ́ 5