Àwọn Adájọ́ 4:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọmọ Israẹli bá tún ké pe OLUWA pé kí ó ran àwọn lọ́wọ́, nítorí pé ẹẹdẹgbẹrun (900) ni kẹ̀kẹ́ ogun Jabini tí wọ́n fi irin ṣe; ó sì ni wọ́n lára fún ogún ọdún.

Àwọn Adájọ́ 4

Àwọn Adájọ́ 4:1-4