Àwọn Adájọ́ 4:2 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA bá fi wọ́n lé Jabini ọba Kenaani, tí ó jọba ní Hasori lọ́wọ́; Sisera, tí ń gbé Haroṣeti-ha-goimu ni olórí ogun rẹ̀.

Àwọn Adájọ́ 4

Àwọn Adájọ́ 4:1-3