Àwọn Adájọ́ 4:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Sisera wí fún un pé, “Jọ̀wọ́ dúró ní ẹnu ọ̀nà àgọ́. Bí ẹnikẹ́ni bá wá, tí ó sì bi ọ́ léèrè pé, ‘Ǹjẹ́ ẹnikẹ́ni wà níbí?’ Wí fún olúwarẹ̀ pé, ‘Kò sí.’ ”

Àwọn Adájọ́ 4

Àwọn Adájọ́ 4:14-21